Inicio Bad Bunny Canciones Religiosas Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Escuchar música y letra de Agbo Ore de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta NewMusicas

Artist profile picture

Agbo Ore

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

Eni to duro, ma duro lele
Eni joko, ma joko tetere
Bo s'agbo ore, ife ma lo pe wa, wa

Ta'lo nse're aladun, (egbe awa ma lo d'ode)
Ta'lo nse're idunnu, (egbe awa ma lo d'ode)
Orin t'o nfun ni l'ayo, (egbe awa ma lo d'ode)
Ilu t'o npe'lu se'jo (egbe awa ma lode)

Wole o, wole wa
Turaka k'o mu ironu sonu
Wole o pelu awon ore
Ife ma lo pe wa, wa

Ta'lo nse're aladun, (egbe awa ma lo d'ode)
Ta'lo nse're idunnu, (egbe awa ma lo d'ode)
Orin t'o nfun ni l'ayo (egbe awa ma lo d'ode)
Ilu t'o npe'lu se'jo (egbe awa ma lode)

Ta'lo nse're aladun, (egbe awa ma lo d'ode)
Ta'lo nse're idunnu, (egbe awa ma lo d'ode)
Orin t'o nfun ni l'ayo (egbe awa ma lo d'ode)
Ilu t'o npe'lu se'jo (egbe awa ma lode)

Wo mi o, wo e
Ijo oni ma tun yato
Pel'awon egbe onidera
Ife ma lo pe wa, wa

Ta'lo nse're aladun, (egbe awa ma lo d'ode)
Ta'lo nse're idunnu, (egbe awa ma lo d'ode)
Orin t'o nfun ni l'ayo (egbe awa ma lo d'ode)
Ilu t'o npe'lu se'jo (egbe awa ma lo d'ode)

Ta'lo nse're aladun, (egbe awa ma lo d'ode)
Ta'lo nse're idunnu, (egbe awa ma lo d'ode)
Orin t'o nfun ni l'ayo (egbe awa ma lo d'ode)
Ilu t'o npe'lu se'jo (egbe awa ma lode)

Eni to duro, jowo ma duro lele
Eni joko, ma joko tetere
Bo s'agbo ore, ife ma lo pe wa, wa

Ta'lo nse're aladun, (egbe awa ma lo d'ode)
Ta'lo nse're idunnu, (egbe awa ma lo d'ode)
Orin t'o nfun ni l'ayo (egbe awa ma lo d'ode)
Ilu t'o npe'lu se'jo (egbe awa ma lo d'ode)

Ta'lo nse're aladun, (egbe awa ma lo d'ode)
Ta'lo nse're idunnu, (egbe awa ma lo d'ode)
Orin t'o nfun ni l'ayo (egbe awa ma lo d'ode)
Ilu t'o npe'lu se'jo (egbe awa ma lode)

Wole wa, wole wa (egbe awa ma lo d'ode)
(Egbe awa ma lo d'ode) wole wa, wole wa
(Egbe awa ma lo d'ode) wole wa, wole wa
(Egbe awa ma lo d'ode) wole wa, wole wa

Más de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

20 canciones
  • Ajosepo
  • Ijo Oni
  • Ikore
  • Kílẹ̀nwò
  • Aimokan
  • Omoniyun
  • A O Dide
  • Agbo Ore
  • Orisimeta
  • Olú Ọdẹ
  • Ilé Ni O Wò
  • Beriwon
  • Guoguo
  • LGLG
  • Alasela
  • Ẹ̀ríỌkàn
  • Omoyeni
  • Igbe Apa
  • À Fi Nkọrin
  • Olumuyiwa
  • Inicio Bad Bunny Canciones Religiosas Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA